Exodus 15:1

Orin Mose àti Miriamu

1 aNígbà náà ni Mose àti àwọn ọmọ Israẹli kọ orin yìí sí Olúwa:

Èmi yóò kọrin sí Olúwa,
nítorí òun pọ̀ ní ògo.
Ẹṣin àti ẹni tí ó gùn ún
ni ó ti sọ sínú Òkun.
Copyright information for YorBMYO